Pheelz, Olamide, Poco Lee, and DJ YK Mule – Lyrics
Enjoy the energetic vibe and captivating rhythm of 5am In Ojo Freestyle by Pheelz, featuring Olamide, Poco Lee, and DJ YK Mule. Dive into the lyrics below and let the music inspire your groove!
Pheelz, Olamide, Poco Lee & DJ YK Mule – 5am In Ojo Freestyle Lyrics
Intro: Poco Lee, Pheelz & DJ YK Mule
DJ YK Mulẹ
Ye pa (Rii, Rii)
Aye lawa n jẹ, Oshaamọ
Tẹwọ, tẹwọ ti o ba sọra, o ma pada tọrọ owo (Rii, Rii)
Ọmọ ase ki lọn wo
Skibi wo ko o
Ọja nla.. wa o
I rep my hood, I don’t know your hood, so rep your hood
Gba number ninu koko
Gbara to wa n ijagbaji
(Ọmọ ọgbọn ti jade tan)
Agege Bariga wa o
Mushin olosa, Mushin olosa
Verse 1: Pheelz
Ọmọ ọgbọn (Skoda), jade tan (L’Eko)
Dey on form (Okay) through the storm
No show your battle scar
Energy dey go far
MJ fun wọn thriller
Fun mi ni cana fa
What is the mathema- ?
Jẹ ka lo s’ariya
Singing like Ayinla
Music is my healer
In the name of Jesus
Violence take it by force
Feel me bi ti..
Feel me bi ti…
Chorus: Pheelz
O lọ far, far (O lọ far o)
O lọ far, far (O lọ far)
O lọ far (O lọ far)
O lọ far, far, far
O lọ far, far (O lọ far)
O lọ far, far
O lọ far, far
O lọ far, far
Bridge: Pheelz
Ko gb’Agege, ko gba Mushin
Ọmọ ma lo seke, aye binti
Ko lọ Federal, ko lọ’gbobi
Dupẹ lọwọ kristi
Alhamdulillah, alhamdulillah, alhamdulillah
